Òjò oníkíkan
Ìrísí
Òjò kíkan (Acid rain) je iru ojo tabi iru isujo miran to unsaba je kikan, eyun pe o ni ipele giga awon ioni haidrojin (pH kekere). O le ni ewu si awon ogbin, awon eranko inu omi, ati si ohun miran oriile to ba fon si won. Idie ti ojo kikan se unsele i nitori itujade sulfur oloksijinmeji ati nitrojin oloksijin ti won undarapo mo awon owon omi ninu afefeayika lati da onikikan.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |