Bùrúndì
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Bùrúndì Republic of Burundi (English) | |
---|---|
Motto: "Ubumwe, Ibikorwa, Iterambere" (Kirundi) "Unité, Travail, Progrès" (Faransé) "Ọ̀kan, Iṣẹ́, Ìrewájú" "Unity, Work, Progress" 1 | |
Orin ìyìn: Burundi bwacu (Our Burundi) | |
Ibùdó ilẹ̀ Bùrúndì (dark blue) – ní Africa (light blue & dark grey) | |
Olùìlú | Bujumbura |
Ìlú tótóbijùlọ | olúìlú |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Kirundi Faransé |
Àwọn èdè ìbílẹ̀ | Kirundi, Swahili |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | Hutu 85% Tutsi 14% Twa 1% |
Orúkọ aráàlú | ará Bùrúndì |
Ìjọba | Orílẹ̀-èdè olómìnira |
• Ààrẹ | Évariste Ndayishimiye |
Prosper Bazombanza | |
Gervais Rufyikiri | |
Aṣòfin | Iléaṣòfin |
Ilé Alàgbà | |
Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin | |
Ìlómìnira | |
• látọwọ́ Ibi-ilẹ̀ Ìdìmú UN tí Bẹ́ljíọ́m sàmójútó | July 1, 1962 (UN Trust Territory) and July 1, 1966 (Independence of the Republic) |
Ìtóbi | |
• Total | 27,834 km2 (10,747 sq mi) (145th) |
• Omi (%) | 7.8 |
Alábùgbé | |
• 2012 estimate | 8,749,000[1] (89th) |
• 2008 census | 8,053,574[2] |
• Ìdìmọ́ra | 314.3/km2 (814.0/sq mi) (45th) |
GDP (PPP) | 2011 estimate |
• Total | $5.184 billion[3] |
• Per capita | $614[3] |
GDP (nominal) | 2011 estimate |
• Total | $2.356 billion[3] |
• Per capita | $279[3] |
Gini (1998) | 42.4[4] Error: Invalid Gini value |
HDI (2010) | ▲ 0.282 Error: Invalid HDI value · 166th |
Owóníná | Burundi franc (FBu) (BIF) |
Ibi àkókò | UTC+2 (CAT) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+2 (not observed) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | ọ̀tún |
Àmì tẹlifóònù | 257 |
ISO 3166 code | BI |
Internet TLD | .bi |
|
Bùrúndì (pipe /bəˈɹʊndɨ/), lonibise bi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Bùrúndì (Kirundi: Republika y'u Burundi, [buˈɾundi]; Faransé: République du Burundi, [byˈʁyndi]), je orile-ede ademolesarin ni agbegbe awon Adagun Ninla ni Apailaorun Afrika to ni bode mo Rwanda ni ariwa, Tanzania ni ilaorun ati guusu, ati Orile-ede Olominira Oloselu ile Kongo ni iwoorun. Oluilu re ni Bujumbura. Botilejepe orile-ede na je ademolesarin, opo bode re ni apa guusuiwoorun wa niwaju Adagun Tanganyika.
Awon Twa, Tutsi, ati Hutu ni won ti ungbe ni Burundi latigba ti orile-ede na ti je didasile ni orundun marun seyin. Burundi je jijoba lelori bi ileoba latowo awon Tutsi fun ogorun meji odun. Sugbon latibere orundun ogun Jemani ati Belgium gba ori ibe won si so ibe di ileamusin to ruko re unje Ruanda-Urundi.
Cobalt ati baba ni meji ninu awon ohun alumoni ti Burundi ni. Bakanna Burundi unta kofi ati suga.
Àwọn ìpínlẹ̀ ìjọba
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Burundi jẹ́ pípín sí ìgbèríko 18,[5] 117 communes,[6] and 2,638 collines (hills).[7] Provincial governments are structured upon these boundaries. In 2000, the province encompassing Bujumbura was separated into two provinces, Bujumbura Rural and Bujumbura Mairie.[8] The newest province, Rumonge, was created on 26 March 2015 from portions of Bujumbura Rural and Bururi.[9]
|
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ World Population Prospects, the 2010 Revision
- ↑ "3rd general census (2008)". Archived from the original on 2013-05-23. Retrieved 2012-06-09.
- ↑ 3.0 3.1 3.2 3.3 "Burundi". International Monetary Fund. Retrieved April 18, 2012.
- ↑ "Distribution of family income – Gini index". The World Factbook. CIA. Archived from the original on May 13, 2009. Retrieved September 1, 2009.
- ↑ 5.0 5.1 Law, Gwillim. "Provinces of Burundi". Statoids. Retrieved 13 July 2015.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedstate
- ↑ Kavamahanga, D."Empowerment of people living with HIV/AIDS in Gitega Province, Burundi". Archived from the original on 19 December 2008. Retrieved 21 July 2008. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) International Conference on AIDS 2004. 15 July 2004. NLM Gateway. Retrieved on 22 June 2008. - ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedxlix
- ↑ Nkurunziza, Pierre (26 March 2015). "LOI No 1/10 DU 26 MARS 2015 PORTANT CREATION DE LA PROVINCE DU RUMONGE ET DELIMITATION DES PROVINCES DE BUJUMBURA, BURURI ET RUMONGE" (PDF). Presidential Cabinet, Republic of Burundi. Archived from the original (PDF) on 25 October 2016. Retrieved 14 July 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Burundi: administrative units, extended". GeoHive. Archived from the original on 14 July 2015. Retrieved 13 July 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)
- Pages with reference errors
- Pages with citations using unsupported parameters
- Articles containing explicitly cited English-language text
- Articles containing Kirundi-language text
- Articles containing Faransé-language text
- Country articles requiring maintenance
- Pages using infobox country with unknown parameters
- Bùrúndì