Jump to content

Ola Opesan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ola Opesan ni a bí ní ọdún 1966 jẹ́ onkòwé, oníròyìn àti olùkọ́ àti ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Brítènì . [1] Ó kọ ìwé rẹ̀ akọ́kọ́ tí ó jẹ́ ìwé ìtàn ọlọ́rọ̀ geere tí ó pe ní Another Lonely Londoner ní ọdún (1991), lábẹ́ ilé-iṣẹ́ òníẹ̀wé pseudonym.

Awọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Opesan's snapshots of Nigerian history, The Guardian, 19 January 2016. Accessed7 December 2020.