Jump to content

Leishmaniasis

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Leishmaniasis
LeishmaniasisCutaneous leishmaniasis in the hand of a Central American adult
LeishmaniasisCutaneous leishmaniasis in the hand of a Central American adult
Cutaneous leishmaniasis in the hand of a Central American adult
Ìpínsọ́wọ̀ àti àwọn òkunfà ìta
ICD/CIM-10B55. B55.
ICD/CIM-9085 085
DiseasesDB3266
MedlinePlus001386

Leishmaniasis tabi leishmaniasis je àrùn kan ti protosan o si ntan kaakiri ni ni kété ti awon kòkòrò kan ba bu ni jẹ. kòkòrò.[1] Kòkòrò na le farahàn lọna mẹta pataki gegebi: kútẹnọs, mukokútẹnọs,tabi fisera lẹṣmaniasisi.[1] Kotẹnọs na ma a nwa pelu ogbe awo-ara,nigbati mukokutẹnọs ma a nwa pelu ọgbẹ awo-ara, enu, ati imu, ati wipe fisera ma a nbẹrẹ pelu ọgbẹ awọ-ara, nigba to ba ya ibà, awon sẹẹli ẹjẹ pupa diẹ, ọlọ inu ati ẹdọ to tobi. [1][2]

O le ni ogun orisiriLẹṣmania ti o nse okùnfa àkóràn arun yi lara eniyan.[1] Awon ohun to fa ewu ni: osi, airiounjẹ-jẹ, pipa igbó run, ati kikun-ilu.[1] Orisi mẹtẹẹta lo se e yẹwo labe ẹrọ mikroskopu. [1] Lafikun, arun fisera se e yẹwo nipa ayẹwo ẹjẹ.[2]

Lẹṣmaniasisi se e daduro nipa sisun labẹ àwọn ti o ni oògun-ẹfọn.[1] Awon igbésẹ miran ni fifi awon kokoro pelu oògun-efon ati titoju awon eniyan ti o ni arun yi lasiko ki o ma ba a tan kalẹ. [1] Iru itoju to ye se e mọ nipa sise awari ibiti won ti ko arun na, awon iru Lẹṣmania, ati iru akoran.[1] Die lara awon oogun lilo fun arun fisera ni: liposoma amfoterisin B,[3] apapọ pentafalenti antimoniasi ati paromomisini,[3] and miltefosine.[4]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 1.5 1.6 1.7 1.8 "Iwe oro otito lori Lẹṣmaniasisi. N°375". World Health Organization. January 2014. Retrieved 17 February 2014. 
  2. 2.0 2.1 Barrett, MP; Croft, SL (2012). "Management of trypanosomiasis and leishmaniasis.". British medical bulletin 104: 175–96. doi:10.1093/bmb/lds031. PMC 3530408. PMID 23137768. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=3530408. 
  3. 3.0 3.1 Sundar, S; Chakravarty, J (Jan 2013). "Lẹṣmaniasisi: famakoterapi ti igbalode.". Iro Amoye lori famakoterapi 14 (1): 53–63. doi:10.1517/14656566.2013.755515. PMID 23256501. 
  4. Dorlo, TP; Balasegaram, M; Beijnen, JH; de Vries, PJ (Nov 2012). "Miltefosine: a review of its pharmacology and therapeutic efficacy in the treatment of leishmaniasis.". The Journal of antimicrobial chemotherapy 67 (11): 2576–97. doi:10.1093/jac/dks275. PMID 22833634.